Nuacht

"Ẹ rántí pé ìdá àádọ́rin ni omi tó yí ilé ayé ká. Fún ìdí èyí, oríire ńlá ló jẹ́ pé orí ilẹ̀ ni òkúta jàbọ̀ sí tí kìí láàárín ...
Atiku ní ìdí tí òun fi ń kọ̀wé fipò sílẹ̀ nínú ẹgbẹ́ náà kò ṣẹ̀yìn àwọn ìyapa ẹnu tó ń wáyé láàárín òun àti ẹgbẹ́ náà.